Friday, December 4, 2020
Home Iroyin Kaycee Madu, ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà di mínísítà fún ètò ìdájọ́ lórílẹ̀...

Kaycee Madu, ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà di mínísítà fún ètò ìdájọ́ lórílẹ̀ èdè Canada


Kaycee Madu, ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà di mínísítà fún ètò ìdájọ́ lórílẹ̀ èdè Canada

Ààrẹ orìlẹ́ èdè Nàíjíríà, Muhammadu Buhari ti gbósùbà ati gbóríyìn fún ọmọ orìlẹ́ èdè Nàíjíríà ,Kaycee Madu, tí wọ́n yàn gẹ́gẹ́ bí minisita fún ètọ̀ ìdájọ́ fún ìjọba Alberta, lórílẹ̀ èdè Canada.

orukọ Madu ti wa ni ninu iwe itan bayii gẹgẹ bi ọmọ orilẹ ede Afirika akọkọ ti yoo kọkọ jẹ minisita lorilẹ ede Canada.

Ademọla Adepọju

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.

Most Popular

Recent Comments

%d bloggers like this: