Saturday, December 5, 2020
Home Iroyin Ìpàdé ìgbìmọ̀ àwọn alásẹ ń lọ lọ́wọ́ nílùú Àbújá

Ìpàdé ìgbìmọ̀ àwọn alásẹ ń lọ lọ́wọ́ nílùú Àbújá


Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Muhammadu Buhari ń ṣe ipade bayii lori ẹrọ ayélujára pẹ̀lú àwọn alásẹ ìgbìmọ̀ nílé ààrẹ nílùú Àbújá.

aarẹ tẹlẹri fun orilẹ ede Naijiria, Goodluck Jonathan naa wa nibi ipade ọhun.

igbakeji aarẹ orilẹ ede Naijiria ,ọjọgbọn Yemi Osinbajo, abẹnugan ile igbimọ asofin agba,Ahmad Lawan ati akọwe agba fun ijọba apapọ , Boss Mustapha naa wa nibi ipade ọhun.

lara awọn to tun wa nibi ipade naa tun ni adari awọn osise fun aarẹ ,ọjọgbọn Ibrahim Gambari ati minisita fun ilu Abuja, Federal Capital Territory (FCT) , Muhammad Bello ati adajọ lorilẹ ede yii ti o tun jẹ ati minisita fun eto idajọ , Abubakar Malami.

awọn miran tun ni aarẹ ana fun orilẹ ede Naijiria ajagun fẹyinti Ibrahim Babangida, Abdusalami Abubakar ati Ernest Shonekan ati awọn gomina ti wọn n darapọ mọ lati ipinlẹ wọn lori ẹrọ ayelujara .

ipade ti wọn se kẹyin waye ni osu kinni , ọdun . 2019.

Ademọla Adepọju

Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.

Most Popular

Recent Comments

%d bloggers like this: