Tuesday, December 1, 2020
Home Iroyin Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ọ̀kan-le-ni-okòó-le-nigba (221)míràn tún ti ní Covid-19

Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ọ̀kan-le-ni-okòó-le-nigba (221)míràn tún ti ní Covid-19


Àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ọ̀kan-le-ni-okòó-le-nigba (221)míràn tún ti ní Covid-19

Ajọ̀ tó ń gbógun ti àjàkálẹ̀ ààrùn lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Nigeria Centre for Disease Control, NCDC ti kéde lórí ẹ̀rọ Twitter wọn @NCDCgov, pé àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà ọ̀kan-le-ni-okòó-le-nigba (221)míràn tún ti ní Covid-19, ní èyí tí ó tún ti jẹ́ kí iye àwọn tí ó ní ààrùn Corona jẹ́ ẹgbẹ́ẹ́ẹdógún-le-ni-ọ̀kẹ́-mèjìaabọ-le-ni- ọ̀kan-le-ni-okòó (53,021),nígbà tí àwọn tí ó ti gba ìwòsàn jẹ́ ọ̀kẹ́-mèjì-le-ni-ọ̀kan-le-ni -ọ́rin-le-nigba (40,281)ti awọn eniyan mẹ́wàá-le-ni-ẹgbẹ́rún(1010) ṣi ti di olóògbé.

Ademọla Adepọju


Leave a Reply

This site uses Akismet to reduce spam. Learn how your comment data is processed.

Most Popular

AWS brings the Mac mini to its cloud – TechCrunch

AWS today opened its re:Invent conference with a...

Facebook acquires Kustomer for $1B – TechCrunch

Facebook makes a billion-dollar acquisition, we learn...

Recent Comments

%d bloggers like this: